Mark 14:27

Jesu sọ àsọtẹ́lẹ̀ pé Peteru yóò sẹ́ òun

27 aJesu sì wí fún wọn pé, “Gbogbo yín ni ẹ ó sa kúrò lọ́dọ̀ mi, a ti kọ̀wé rẹ pé:

“ ‘Èmi yóò lu olùṣọ́-àgùntàn
àwọn agbo àgùntàn yóò sì fọ́nká.’
Copyright information for YorBMYO